Wikipedia:Civility
![](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/6/65/Jimmy_Carter_greets_residents_of_South_Bronx%2C_New_York_-_NARA_-_176402.tif/lossy-page1-200px-Jimmy_Carter_greets_residents_of_South_Bronx%2C_New_York_-_NARA_-_176402.tif.jpg)
Ìwà ìrẹ̀lẹ̀ jẹ́ ara ìṣe wa ní Wikipedia, ó sì wà lára òpó marún tí ó gbé Wikipedia ró. Ètò ìmúlò yìí ṣe àlàyé nípa bí a ṣe fẹ́ kí oníṣẹ́ ṣe máa dojú kọ ìṣòro tí wọ́n bá yọjú. Níwọ̀nba, àwọn olóòtú gbọ́dọ̀ ḿa bọ̀wọ̀ fún ara wọn. Kí wọ́n máa gbìyànjú lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìwé-ìmọ ọ̀fẹ́ kí wọ́n sì máa hu ìwà tó dára, pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀, ìwà tútú, pàápàá jùlọ tí ìtàkùrọ́sọ̀ bá ń gbóná jinjin. Ìwà ìrẹ̀lẹ̀ tí Wikipedia fẹ́ níṣe pẹ̀lú gbogbo àwọn olóòtú nígbà tí wọ́n bá ń bá ara wọn sọ̀rọ̀ ní Wikipedia, pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ní ojú ewé ọ̀rọ̀ oníṣẹ́ àtí ojú ewé ọ̀rọ̀ àyọkà àti gbogbo ìjíròrò pèlú tàbí nípa àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ tí ó jẹ́ olùkọ Wikipedia.
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipediaTübingenWikipedia:Nípa WikipediaYunifásítì ìlú TübingenÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÀrokòÒgún LákáayéṢàngóEre idarayaỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè HíndìWikiWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáWikipedia:Àyọkà pàtàkìBenjamin NetanyahuSpike LeeCharlotte RamplingGeorg Wilhelm Friedrich HegelWọlé SóyinkáLítíréṣọ̀Pàtàkì:SearchWikipedia:Abẹ́ igiÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunIṣẹ́ Àgbẹ̀William RamsayÌwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNUÀṣà YorùbáMaryam YahayaGeographic coordinate systemGbólóhùn YorùbáDerek WalcottIllinoisIfáWhake