Mercedes Ruehl

Mercedes Ruehl ni a bini ọjọ kèji dinlọgbọn óṣu february ni ọdun 1948 jẹ Óṣèrè lobinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Mercedes Ruehl
Ruehl in 2009
Ọjọ́ìbíMercedes J. Ruehl
28 Oṣù Kejì 1948 (1948-02-28) (ọmọ ọdún 76)
Jackson Heights, Queens
Ẹ̀kọ́College of New Rochelle
Pacific Conservatory of the Performing Arts
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1976–present
Olólùfẹ́
David Geiser
(m. 1999; died 2020)
Àwọn ọmọ2
Àwọn olùbátanPeter Ruehl (brother)

Igbèsi Àyè Àràbinrin naa

Ruehl ni a bisi Jackson Heights, Queens, New York City fun Mercedes J. Ruehl (Ólukọ) ati Vincent Ruehl (Agenti ti FBI)[2]. Babà óṣèrè lobinrin naa wa lati iràn German ati Irish, Iya rẹ wa lati iran Cuban ati Irish. Ruehl ni ó dàgbà si ilanà Catholic[3].

Óṣèrè lobinrin naa bẹrẹ irin àjó iṣẹ rẹ ni theatre pẹlu Ilè iṣẹ Denver Center Theatre.Ni ọdun 1999, Ruehl fẹ David Geiser ti ó jẹ painter. Óṣèrè gba ọmọ ọkunrin kan tọ ti órukọ rẹ njẹ Jake ti a bini ọdun 1995. David Geiser ku lójiji ninu órun rẹ ni ilè rẹ ni ọjọ kẹrin dinlógun óṣu October ni ọdun 2020 lori aisan ọkan[4][5].

Ẹkọ

Ruehl lọsi collegi ti New Rochelle ti ó si kàwè ja pẹlú BA lori èdè gẹẹsi ni ọdun 1969[6].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

ỌdunÀkọlèAccoladeÈsi
1989Married to the MobNational Society of Film Critics Award, Best Supporting ActressÓṣèrè lóbinrin naa yègè
1991The Fisher KingBoston Society of Film Critics Award, Best Supporting ActressÓṣèrè lóbinrin naa yègè
Lost in YonkersDrama Desk Award, Outstanding Actress in a PlayÓṣèrè lóbinrin naa yègè
The Fisher KingLos Angeles Film Critics Association Award, Best Supporting ActressÓṣèrè lóbinrin naa yègè
Lost in YonkersTony Award, Best Performance by a Leading Actress in a PlayÓṣèrè lóbinrin naa yègè
The Fisher KingVenice Film Festival Award, Best Lead ActressÓṣèrè lóbinrin naa yègè
1992Academy Award, Best Supporting ActressÓṣèrè lóbinrin naa yègè
American Comedy Award, Funniest Supporting Actress in a Motion PictureÓṣèrè lóbinrin naa yègè
Chicago Film Critics Association Award, Best Supporting ActorÓṣèrè lóbinrin naa yègè
Dallas-Fort Worth Film Critics Association Award, Best Supporting ActressÓṣèrè lóbinrin naa yègè
Golden Globe Award, Best Supporting Actress in a Motion PictureÓṣèrè lóbinrin naa yègè
Saturn Award, Best Supporting ActressÓṣèrè lóbinrin naa yègè
1993Boston Film Festival Award, Film Excellence awardÓṣèrè lóbinrin naa yègè
1995Indictment: The McMartin TrialCableACE Award, Best Actress in a Movie or MiniseriesWọn yan
The Rose TattooDrama Desk Award, Outstanding Actress in a PlayWọn yan
The Shadow BoxTony Award, Best Performance by a Featured Actress in a PlayWọn yan
2002The Goat, or Who Is Sylvia?Tony Award, Best Performance by a Leading Actress in a PlayWọn yan
2006Mom at SixteenPrism Award, Performance in a Television Movie or MiniseriesWọn yan
2007A Girl Like Me: The Gwen Araujo StoryImagen Foundation Award, Best Actress - TelevisionWọn yan

Itokasi