Marcia Gay Harden

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Marcia Gay Harden ni wọ́n bí ní ọjọ́ kerìnlá, oṣù kẹjo ọdún 1959 jẹ́ òṣèrébinrin Orílẹ̀ èdè America tó ti gba orisirisi ebún bi Ebun Akademi, ati Tony Award.[1]

Marcia Gay Harden
Harden in 2013
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹjọ 1959 (1959-08-14) (ọmọ ọdún 64)
La Jolla, California, U.S.
Ẹ̀kọ́University of Texas, Austin (BA)
New York University (MFA)
Iṣẹ́Òṣérébinrin
Ìgbà iṣẹ́1979–present
Olólùfẹ́
Thaddaeus Scheel
(m. 1996; div. 2012)
Àwọn ọmọ3
AwardsFull list

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́

Wọ́n bí sí La Jolla, California, omo-bíbi Beverly Harden (née Bushfield).[2] Harden parí ní ile eko girama ti Surrattsville, Clinton, Maryland ni odun 1976.O parí ni Yunifasiti Texas to wa ni olúlú Austin ni odun 1980. O keko gboye Masters of Fine Arts lati fásitì New York University's Tisch School of Arts ni odun 1988.[3]

Itokasi