Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

(Àtúnjúwe láti List of Governors of Oyo State)

Èyí ni àtòjọ àwọn alámójútó àti àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní Nàìjíríà. Wọ́n dá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sílẹ̀ ní ọdún 1976-02-03 nígbàtí Western Region jẹ́ pípín sí àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́ta ìpínlẹ̀ Ogun, Ondo, àti Oyo.

NameTitleTook OfficeLeft OfficePartyNotes
Col. David Medaiyese JemibewonGovernor19751978(Military)
Col. Paul C. TarfaGovernor19781979(Military)
Chief Bola IgeExecutive Governor19791983
Dr. Victor Omololu OlunloyoExecutive Governor19831983
Lt. Col. Oladayo PopoolaGovernor19841985(Military)
Col. Adetunji Idowu OlurinGovernor19851988(Military)
Col. Sasaenia OresanyaGovernor19881990(Military)
Col. Abdul Kareem AdisaGovernor19901992(Military)
Chief Kolapo Olawuyi IsholaExecutive Governor19921993
Navy Capt. Adetoye Oyetola SodeAdministrator19931994(Military)
Col. Chinyere Ike NwosuAdministrator19941996(Military)
Col. Ahmed Usman Administrator19961998(Military)
Comm. Pol. Amen Edore Oyakhire Administrator16 August 199828 May 1999(Military)
Dr. Lam Onaolapo Adesina Governor29 May 199928 May 2003Oloselu
Rasheed LadojaGovernorMay 29, 2003May 28, 2007Impeached in January 2006, reinstated in December 2006
Christopher Alao-AkalaGovernor (de-facto)January 12, 2006December 7, 2006Appointed when Rasheed Ladoja was been impeached, until the impeachment was overturned.
Christopher Alao-AkalaGovernorMay 29, 2007May 29, 2011Oloselu
Abiola AjimobiGomina AdiboyanMay 29,2011May 29,2019Oloselu
Seyi MakindeGomina AdiboyanMay 29 2019PresentOloselu


See also

References