Kris draper

Kristopher Bruce "Kris" Draper (tí wọ́n ní oṣù kàrún-un ọdún 1971) sí Canada jẹ́ ọ̀kan lára Eléré Agbá Hockey, tí ó sì jẹ́ Olùdarí Àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́ fún àwọn ṣẹ̀ṣẹ̀dé àti Olùrànlọ́wọ́ gbogbogbò fún Detroit Red Wings, tí ẹgbẹ́ rẹ̀ sí gbà Hockey fún sáà mẹ́tàdínlógún ní gbogbo ìgba tó fí gbà Hockey.

Born24 Oṣù Kàrún 1971 (1971-05-24) (ọmọ ọdún 53),
Toronto, Ontario, Canada
Height
Weight
5 ft 10 in (1.78 m)
188 lb (85 kg; 13 st 6 lb)
PositionCentre
ShootsLeft
Pro clubsWinnipeg Jets
Detroit Red Wings
Ntl. teamÀdàkọ:Ih
NHL Draft62nd overall, 1989
Winnipeg Jets
Pro career1989 – 2011

Draper tí gbà Àmi ẹ̀yẹ Stanley Cup ní ẹ̀ẹ̀mẹrin ọ̀tọ́tọ̀ ní Detroit, o tún jẹ́ eni tí ó gbà Àmi ẹ̀yẹ Frank J. Sells, ó sí tí gbà bọ́ọ̀kù sí àwọ̀n ni ìgbà ọgọ́rùn-ún ní igbà tí ó ń gbà Hockey pẹ̀lú Red Wings. Draper jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tí ó ní òkìkí ní Grind Line] ní Detroit, ti àwọn akẹgbẹ́ rẹ sí jẹ́ Kirk Maltby àti Joe Kocur tabi Darren McCarty. Àwọn Eré ìparí 222 rẹ̀ẹ jẹ́ kí ó wà ní ipo kẹwàá ní Atoókọ ti àwọn Olùdarí ìṣirò NHL #Playoff.

Àwọn iṣé lẹ́yìn eré

Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ lẹ́yìn ìfẹ̀yìntì Draper nídì iṣé hockey, Wọ́n gbàá sí iṣé Red Wings gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára Òṣìṣẹ́ ọ́fìsì.Ó ti ṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀ rí bí olùrànlọwọ pàtàkì sí olùṣàkóso gbogbogbò, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ken Holland.

Ní ipò yìí, Draper ṣiṣẹ́ ní pẹ́kípẹ́kí pẹ̀lú ẹgbẹ́ ìṣàkóso Detroit, láti ṣe ìrànlọ́wọ́ ìgbéléwọ̀n fún àwọn eléré Hockey fún àwọn tí wọn sẹ̀sẹ̀ bè àti àwọn tí wọn tì dì àgbà ọ̀jẹ̀ tàbí ọ̀jọ̀gbọ́n nínú eré Hockey.

Wọn yóò béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ láti pèsè ìgbéwòlè nípa àwọn ìṣòwò tí ó pọ́jú àti àwọn ìforúkọsílẹ aṣojú ọ̀fẹ́, àti pèsè òye sí àwọn yíyan tí ó pọ̀jù ní àkópamọ́ NHL lọ́dọọdún.

Ni osù keje, ọdún 2019, Draper ní ìgbéga sí ipò Olùdarí àwọn ṣẹ̀ṣẹ̀ dé, eyi tí  Steve Yzerman tí ó jẹ́ akẹgbẹ re náà wà ní ipò olùṣàkóso gbogbogbò tuntun, lẹ́yìn tí Tyler Wright kúrò lọsí Edmonton. Ní oṣù keje náà ní ọdún 2023, Ó tún rí ìgbéga sí Red wing gẹ́gẹ́ bí olùrànlọwọ Kejì sí Olùdarí gbogbogbò.[1]

Igbé ayé

Draper àti aya rere ní ọmọ Obìnrin Méjì, Kenndi àti Kamryn, oẹ̀lú ọkùnrin kàn, Keinan.Kienan wà l'ára àwọn tí Saginaw Spirit yàn ní round kẹjọ ní Ontario Hockey League ní ọdún 2018.[2][3] He played for the Chilliwack Chiefs of the British Columbia Hockey League during the 2020–2021 season, and currently plays for the Michigan Wolverines.[4][5] Kienan was drafted in the seventh round, 187th overall, overall by the Detroit Red Wings in the 2020 NHL Entry Draft.[6]

Ere òkèrè

Medal record
Adíje fún Canada
Men's ice hockey
World Championships
Wúrà2003 Finland
Fàdákà2005 Austria
World Cup of Hockey
Wúrà2004 Canada
World Junior Championships
Wúrà1991 Canada
Wúrà1990 Finland

Draper participated in eight international tournaments for Canada:

  • 1990 World Junior Ice Hockey Championships
  • 1991 World Junior Ice Hockey Championships
  • 2000 IIHF World Championship
  • 2001 IIHF World Championship
  • 2003 IIHF World Championship
  • 2004 World Cup of Hockey
  • 2005 IIHF World Championship
  • 2006 Winter Olympics

Career statistics

Regular season and playoffs

  Regular season Playoffs
SeasonTeamLeagueGPGAPtsPIMGPGAPtsPIM
1987–88Don Mills Flyers Midget AAAMTHL4035326746
1988–89Canadian National TeamIntl6011152616
1989–90Canadian National TeamIntl6212223444
1990–91Ottawa 67'sOHL3919426135178111920
1990–91Moncton HawksAHL72132
1990–91Winnipeg JetsNHL31015
1991–92Moncton HawksAHL6111182911340116
1991–92Winnipeg JetsNHL10202220000
1992–93Moncton HawksAHL6712233540522418
1992–93Winnipeg JetsNHL70002
1993–94Adirondack Red WingsAHL4620234349
1993–94Detroit Red WingsNHL3958133172244
1994–95Detroit Red WingsNHL36268221841512
1995–96Detroit Red WingsNHL527916321842618
1996–97Detroit Red WingsNHL768513732024612
1997–98Detroit Red WingsNHL64131023451913412
1998–99Detroit Red WingsNHL804141879100116
1999–00Detroit Red WingsNHL5157122892026
2000–01Detroit Red WingsNHL75817253860112
2001–02Detroit Red WingsNHL82151530562323520
2002–03Detroit Red WingsNHL821421358240004
2003–04Detroit Red WingsNHL6724164031121346
2005–06Detroit Red WingsNHL801022325860006
2006–07Detroit Red WingsNHL81141529581820224
2007–08Detroit Red WingsNHL659817682231410
2008–09Detroit Red WingsNHL79710174081010
2009–10Detroit Red WingsNHL8171522281200016
2010–11Detroit Red WingsNHL4765111280112
NHL totals1,157161203364790222242246160

International

YearTeamEventResult GPGAPtsPIM
1990CanadaWJCÀdàkọ:Goca70224
1991CanadaWJCÀdàkọ:Goca71340
2000CanadaWC4th31010
2001CanadaWC5th71230
2003CanadaWCÀdàkọ:Goca903310
2004CanadaWCHÀdàkọ:Goca52242
2005CanadaWCÀdàkọ:Sica90226
2006CanadaOG7th60000
Junior totals141564
Senior totals39491318

Àmì Ẹ̀yẹ àti Àmì ìyìn

AwardYear
NHL
Stanley Cup1997, 1998, 2002, 2008
Frank J. Selke Trophy2004[7]

Ẹ tún wo

  • List of NHL players with 1000 games played

Àwọn Ìtọ́kasí


  • Àdàkọ:Icehockeystats
Àdàkọ:S-end
Preceded by
Jere Lehtinen
Winner of the Frank J. Selke Trophy
2004
Succeeded by
Rod Brind'Amour