Gloria Gaynor

Gloria Gaynor(orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Gloria Fowles; tí a sì bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹsàn ọdun 1943[1][2][3]) jẹ́ akorin ará Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ fún àwọn orin disco rẹ̀; "I Will Survive", "Never Can Say Goodbye", "Let Me Know (I Have a Right)" àti "I Am What I Am".[4][5]

Gloria Gaynor
Gaynor in 2012
Gaynor in 2012
Background information
Orúkọ àbísọGloria Fowles
Ọjọ́ìbí7 Oṣù Kẹ̀sán 1943 (1943-09-07) (ọmọ ọdún 80)
Newark, New Jersey, U.S.
Irú orin
  • Disco
  • R&B
  • Post-disco
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
Years active1965–present
LabelsJocida (1965)
MGM (1965–76)
Polydor (1976–83)
Chrysalis (1984–85)
Stylus (1986–88)
Hot Productions (1996–97)
Logic (2000–04)
Radikal (2005–present)
Associated actsSoul Satisfiers, Marvin Gaye, Luther Vandross
Websitegloriagaynor.com

Ìpìlẹ̀ ayé rẹ̀

A bí Gaynor sínú ìdílé Daniel Fowles àti Queenie Mae Proctor ní Newark, New Jersey,[6]. Ìyá bàbá tàbí màmá rẹ̀ ń gbẹ ní ẹgbẹ́ ilé tí wón bi sí, òun sì ló tọ́ Gaynor dàgbà.[7] "Orin ma ń wà ní ilé wa ní gbogbo ìgbà", Gaynor ko nínú ìwé ìtàn ayé rẹ̀; I Will Survive.

Ayé rẹ̀

Gaynor fẹ́ Linwood Simon ní ọdun 1979. Àwọn méjèjì kọ ara wọn sílè ní ọdun 2005.[8] Wọn kò bí ọmọ kọkan. Gẹ́gẹ́ bí Gaynor ṣe sọ, bí ó tilè jẹ́ wípé ó fẹ́ bí ọmọ, Linwood kò fẹ́ ọmọ.[9]

Àwọn Ìtọ́kasí