Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì (USA)

Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì ni ikan ninu awon egbe oloselu ninla meji igba oni ni Amerika, po mo Egbe Republikani. Idurole alanidekun awujo ati arewaju egbe na je gbigba bi arin-owo-osi ninu ibu oselu Amerika.[1][2][3] Egbe yi ni rekodu isise ni Amerika togunjulo, be sini o je ikan larin awon egbe oloselu to gbojulo lagbaye.[4] Egbe yii ni omo-egbe milionu 72 ti o ti foruko sile ni odun 2004.[5] Ogbeni Barack Obama ni Demokrati 15k ti yio bo sipo Aare orile-ede Amerika.

Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì
Democratic Party
ChairpersonTom Perez
Senate LeaderChuck Schumer (Minority Leader) (NY)
House LeaderNancy Pelosi (CA)
Chair of Governors AssociationJay Inslee (WA)
Ìdásílẹ̀1828 (modern)
1792 (historical)
Ibùjúkòó430 South Capital Street SE,
Washington, D.C., 20003
Ẹ̀ka akẹ́kọ̀ọ́College Democrats of America
Ẹ̀ka ọ̀dọ́Young Democrats of America
Ọ̀rọ̀àbáModern:
American liberalism
Third Way
Progressivism
Internal factions:
 • Progressive Democrats
 • Libertarian Democrats
 • Moderate Democrats
 • Conservative Democrats
Historical:
Jacksonian democracy
Classical liberalism
Bimetallism
States' rights
Paleoconservatism
Ìbáṣepọ̀ akáríayéAlliance of Democrats
Official colorsBlue
Position in national political spectrumCenter-left
Seats in the Senate
47 / 100
Seats in the House
194 / 435
Governorships
16 / 50
State Upper Houses
921 / 1,921
State Lower Houses
2,368 / 5,410
Ibiìtakùn
http://www.democrats.org/


Itokasi