C++

C++ (ti an pe ni "cee pilus pilus") o je kiko ti o duro, form ofe language, orisirisi-paradigm, ti a compili, iwulo gbogboede programming. A o ma pe ni ede aarin, nitori wipe o ni awon irinse |ede ti o ga]] ati ede ti o kere.[1] Bjarne Stroustrup ni eni ti o da ede yi sile lati odun 1979 ni Bell Labs gege bi ilosiwaju fun ede C. Eyin ti oruko ipinle re n je C pelu kilaasisi, won so ede naa ni C++ ni odun 1983.[2]

Ìdá lórí C++.

C++ je ikan lara awon ede ti o gbajumo[3][4] pelu apilication domain ti o ni sisitem software ninu (gege bi Microsoft Windows), application software, device drivers, embedded software, high-performance server ati client applications, pelu software idaraya gege bi video games.[5] ai moye akojopo ni o man pese C++ ofe ati propreitary compiler software, pelu GNU Project, Microsoft, Intel ati Embarcadero Technologies. C++ ti je arikoshe ti o ni agbara fun awon ede programming yoku tio gbajumo , e yin ti o gbajumo ju C# ati Java.

A tun ma nlo C++ fun hardware design, ni ibi ti a ti koko se apejuwe design ni C++, ti a se ijiroro re, architecturally constrained, ati gbigba aye lati da register-transfer level hardware description language via high-level synthesis.[6]


Itokasi