Bólshéfìk

Àwọn Bólshéfìk, ni bere bi[1] Bolshevists[2] (Rọ́síà: большевики, большевик (singular) Pípè ní èdè Rọ́síà: [bəlʲʂɨˈvʲik], to wa lati bol'shinstvo, "ogunlogo", to hun na wa lati bol'she, "ju", iru oro ijuwe bol'shoi, "titobi") ni won je eka Marxisti Egbe Olosise Tolosearailu Awujo Rosia (RSDLP) to pin soto lodo eka Menshefik[3] ni ibi Kongres Keji Egbe ni 1903.

"Bolshevik", ikunoda Boris Kustodievni 1920



Itokasi