Bàtà

Bàtà jẹ́ ohun tí ọmọ ènìyàn ma ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ láti lè fi rìn ati láti se dáàbòbò ẹsẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìjàmbá tó lè ṣakóbá fún ẹsẹ̀ [1]

Bata ideja
Àpẹẹrẹ bàtà tí wọ́n figi gbẹ́

Ìwúlò bàtà

Wọ́n ma ń lo bàtà yálà lásìkò ẹ̀rùn tàbí òjò. Wọ́n ń lo bàtà láti fi ṣe iṣẹ́ èyíkéyí, ṣe eré ìdárayá, ṣe ìdáàbòbò ara àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [2] Láì Ko sí bàtà láyé Òde òní, ó lè ṣòro fún ọmọnìyàn láti ṣe ohunkóhun dára dára bí wọn Ko bá wọ bàtà sí ẹsẹ̀.

Àwọn Ìtọ́kasí