Arméníà

Arméníà (Gbígbọ́i /ɑrˈmniə/; Arméníà: Հայաստան, siso Hayastan, IPA: [hɑjɑsˈtɑn]), fún iṣẹ́ọba bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Arméníà (Հայաստանի Հանրապետություն, Hayastani Hanrapetut’yun, [hɑjɑstɑˈni hɑnɾɑpɛtuˈtʰjun]), je orile-ede oke-ile ti ile yika ni agbegbe Kafkasu ni Eurasia. O budo si oritameta Apaiwoorun Asia ati Apailaorun Europe,[14] o ni bode mo Turki ni iwoorun, Georgia ni ariwa, de facto Nagorno-Karabakh Republic alominira ati Azerbaijan ni ilaorun, ati Iran ati ile Azerbaijani Nakhchivan ni guusu.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Arméníà
Republic of Armenia

  • Հայաստանի Հանրապետություն (Armenian)
  • Hayastani Hanrapetut’yun
Orin ìyìn: Մեր Հայրենիք
Mer Hayrenik
("Our Motherland")
Location of Arméníà
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Yerevan
40°11′N 44°31′E / 40.183°N 44.517°E / 40.183; 44.517
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaArmenian[1]
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2011)
Ẹ̀sìn
Armenian Apostolic Church[4]
Orúkọ aráàlúArmenian
ÌjọbaUnitary parliamentary republic
• President
Vahagn Khachaturyan (Վահագն Խաչատուրյան)
• Prime Minister
Nikol Pashinyan (Նիկոլ Փաշինյան)
• President of the National Assembly
Alen Simonyan (Ալեն Սիմոնյան)
AṣòfinNational Assembly
Establishment history
• Orontid dynasty
6th century BC
• Kingdom of Greater
Armenia united under
the Artaxiad Dynasty[6]
190 BC[5]
• Arsacid dynasty
52–428
• Bagratid Armenia
885–1045
• Kingdom of Cilicia
1198–1375
• First Republic of Armenia declared

28 May 1918
1936-1991
• Independence from the Soviet Union
21 September 1991
Ìtóbi
• Total
29,743 km2 (11,484 sq mi) (138th)
• Omi (%)
4.71[7]
Alábùgbé
• 2020 estimate
2,956,900 [8] (137th)
• 2011 census
3,018,854 [9][10]
• Ìdìmọ́ra
101.5/km2 (262.9/sq mi) (99th)
GDP (PPP)2019 estimate
• Total
$32.893 billion[11]
• Per capita
$10,995[11]
GDP (nominal)2019 estimate
• Total
$13.444 billion[11] (127th)
• Per capita
$4,527[11] (104th)
Gini (2018)Àdàkọ:IncreaseNegative 34.4[12]
medium
HDI (2018) 0.760[13]
high · 81st
OwónínáDram (֏) (AMD)
Ibi àkókòUTC+4 (AMT)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù+374
ISO 3166 codeAM
Internet TLD

45°E / 40°N 45°E / 40; 45



Itokasi