Aliyu Mai-Bornu
olutọju ile Naijiria
Mallam Aliyu Mai-Bornu tí wọ́n bí ní ọdún 1919, tí ó sì ṣaláìsí lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 1970 (1919 - 23 February 1970) jẹ́ òkúná-gbòǹgbò onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ tó jẹ́ Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà.[1]
Aliyu Mai-Bornu | |
---|---|
Governor of the Central Bank of Nigeria | |
In office Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1963 – Ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹfà ọdún 1967 | |
Asíwájú | Roy Pentelow Fenton |
Arọ́pò | Clement Nyong Isong |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọdún 1919 |
Aláìsí | Ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 1970 |
Àwọn ìtọ́kasí
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìẸ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1956Pàtàkì:SearchWikipediaÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáEre idarayaPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáf9qfoỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)ÀrokòWikipedia:Èbúté ÀwùjọṢàngóFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgÈdè YorùbáÒgún LákáayéIṣẹ́ Àgbẹ̀Wikipedia:Abẹ́ igiDavid EjoorWikipedia:Nípa WikipediaCristiano RonaldoÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíÀṣà YorùbáMediaWikiFinidi GeorgeWikipedia:Ìṣẹ̀lẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́Owe YorubaFáwẹ̀lì YorùbáWikipedia:Àyọkà pàtàkìÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáMagnesiumÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Wikipedia:NípaGbólóhùn YorùbáẸ̀ka:Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́Akanlo-edeGírámà YorùbáOsinlokun