Abraham Lincoln
Abraham Lincoln (i/ˈeɪbrəhæm ˈlɪŋkən/; Ọjọ́ kejìlá Oṣù kejì Ọdún 1809 – Ọjọ́ karùndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún1865) jẹ́ ààrẹ United States kẹrìndínlógún, tí ó ṣèjọba láti Oṣù kẹta Ọdún 1861 dí Oṣù kẹrin Ọdún 1865 tí wọ́n ṣekú paá. Lincoln jẹ́ olórí orílẹ̀ èdè United States nígbà ogún abẹ́lé ìlú náà—Ogun ìtàjẹ̀sílẹ̀ tí ó pọ̀ tí ó jẹ́ tí ìtẹríba, òfin àti rògbòdìyàn òṣèlú.[1][2] Ní ogun jíjà yìí ó dá ìṣọ̀kan sí, ó fi òpin sí òwò ẹrú, fún ìjọba lágbára, ó sì jẹ́ kí ìlọsíwájú bá okòwò ìlú.
Abraham Lincoln | |
---|---|
![]() | |
16th President of the United States | |
In office March 4, 1861 – April 15, 1865 | |
Vice President | Hannibal Hamlin (1861–1865) Andrew Johnson (1865) |
Asíwájú | James Buchanan |
Arọ́pò | Andrew Johnson |
Member of the U.S. House of Representatives from Illinois's 7th district | |
In office March 4, 1847 – March 3, 1849 | |
Asíwájú | John Henry |
Arọ́pò | Thomas L. Harris |
Member of the Illinois House of Representatives | |
In office 1834–1842 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Hodgenville, Kentucky, U.S. | Oṣù Kejì 12, 1809
Aláìsí | April 15, 1865 Petersen House, Washington, D.C., U.S. | (ọmọ ọdún 56)
Resting place | Lincoln Tomb, Oak Ridge Cemetery Springfield, Illinois, U.S. |
Ọmọorílẹ̀-èdè | American |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Whig (1834–1854) Republican (1854–1865) |
Other political affiliations | National Union (1864–1865) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Mary Todd (m. 1842; his death 1865) |
Àwọn ọmọ | Robert, Edward, Willie, and Tad |
Profession | Lawyer Politician |
Signature | ![]() |
Military service | |
Allegiance | ![]() |
Branch/service | Illinois Militia |
Years of service | 3 months (April 21, 1832 – July 10, 1832) |
Rank |
|
Battles/wars | Black Hawk War |
Wọ́n bíi ní Hodgenville, Kentucky, Lincoln dàgbà sí ìwọ oòrùn frontier ní Kentucky àti Indiana. Ókpọ ara rẹ̀ ní ìwé, ó di agbẹ́jọ́ro ní Illinois, Olórí Ẹgbẹ́ Òṣèlú Whig àti ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti lllinois ní ibi tí ó ti lo ọdún méjìlá. Wọ́n yàn án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti United States ní Ọdún 1846, Lincoln mú ìlọsíwájú ba okòwo látàrí ilé-ìfowópamọ́, owó orí ìṣòwò lókèèrè àti ojú irin.
Àwọn ìtọ́kasí
Ìwé ìtàn
- Burkhimer, Michael (2003). One Hundred Essential Lincoln Books. Cumberland House. ISBN 978-1-58182-369-1.
- Foner, Eric (2008). Our Lincoln: New Perspectives on Lincoln and His World. W.W. Norton. ISBN 978-0-393-06756-9.
- Holzer, Harold and Craig L. Symonds, eds. Exploring Lincoln: Great Historians Reappraise Our Greatest President (2015), essays by 16 scholars
- Manning, Chandra, "The Shifting Terrain of Attitudes toward Abraham Lincoln and Emancipation", Journal of the Abraham Lincoln Association, 34 (Winter 2013), 18–39.
- Smith, Adam I.P. "The 'Cult' of Abraham Lincoln and the Strange Survival of Liberal England in the Era of the World Wars", Twentieth Century British History, (Dec 2010) 21#4 pp. 486–509
- Spielberg, Steven; Goodwin, Doris Kearns; Kushner, Tony. "Mr. Lincoln Goes to Hollywood", Smithsonian (2012) 43#7 pp. 46–53.