Abdulla Baba Fatadi

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Abdulla Baba Fatadi tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejì Oṣù Kọkànlá ọdún 1985 (2nd November 1985) jẹ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Bahraini.[3] Ó jẹ́ olùdarí fún ẹgbẹ́ Al Jahra . Orukọ àbísọ rẹ̀ ni Babatunde Fatai. Ó gbá Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Naijirialábala àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ tí ọjọ́ orí wọ́n kò ju mẹ́tàdínlógún (17) lọ kí ó tó sọ ara rẹ̀ di ará orilẹ-èdè Bahrain lọ́dún 2004.

Abdullah Baba Fatai
Personal information
OrúkọBabatunde Fatai-Baba Fatai
Ọjọ́ ìbí2 Oṣù Kọkànlá 1985 (1985-11-02) (ọmọ ọdún 38)
Ibi ọjọ́ibíLagos, Nigeria
Ìga1.76 m (5 ft 9 in)
Playing positionMidfielder[1]
Youth career
2000–2002Osaka Fc Lagos
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2002–2004Al Najma Club31(13)
2004–2006Al Ahli Club28(12)
2006–2008Muharraq Club30(14)
2008–2009Al-Kharitiyath S.C.23(2)
2009–2010Neuchâtel Xamax17(1)
2010–2011w:Ittihad Kalba10(0)
2011Al-Qadisiyah FC[2]10(1)
2011–2012Al Jahra19(3)
2012–2013Al-Shoalah11(0)
Al-Hidd
National team
2007–2012Bahrain46(8)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 1 August 2011.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 17 October 2011

Awọn ifojusi fun ẹgbẹ orilẹ-ede giga

#ỌjọIbugbeAlatakoO woleEsiIdije
21 Oṣu Kẹwa 2007Manama , BahrainMalaysia4-1WonFIFA Iwọn Agbaye FIFA 2010
16 January 2007Manama , Bahrain  Kuwait1-0WonOre
26 January 2008Manama , Bahrain  Yemen2-1WonOre
10 Kẹsán 2008Doha , Qatar  Qatar1-1FọFIFA Iwọn Agbaye FIFA 2010
21 January 2009Hong Kong , Hong Kong  ilu họngi kọngi3-1Won2011 AFC Asian Cup qualification
23 Oṣù 2009Manama , Bahrain  Zimbabwe5-2WonOre
18 Kọkànlá Oṣù 2009Manama , Bahrain  Yemen4-0Won2011 AFC Asian Cup qualification
29 Kọkànlá Oṣù 2011Aden , Yemen  Apapọ Arab Emirates1-3Isonu2010 Gulf Cup of Nations

Awọn itọkasi