Ẹranko elégungun

Ẹranko elégungun /ˈvɜːrtəˌbrəts/ ni ó kó gbogbo ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ́ lára ẹbí (subphylum) ẹranko elégungun ma ń sábà ní /ʔə/ chordates (egungun ẹ̀yìn). Ẹranko elégungun ni wọ́n jẹ́ púpọ̀ níní ẹbí phylumChordata, tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lé láàdọ́rin àti ọgórùn ún ó dín méje (69,963) níye ẹ̀yà tí a gbọ́ nípa wọn.[4] Lála àwọn àkójọpọ̀ àwọn ẹranko elégungun ni:

  • ẹja aláìnírùngbọ̀n
  • Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun onírùngbọ̀, ni a ti lè rí àwọn ẹranko bíi ẹjà cartilaginous (ẹja ṣáàkì, rays, àti ratfish)
  • Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun tetrapods,ni a ti lè rí amphibians, afàyàfà, ẹyẹ àti àwọn ẹranko afọ́mọlọ́mú gbogbo.
  • ẹja eléegun púpọ̀[5] [6]
Ẹranko elégungun
Vertebrate
Temporal range:
Cambrian–Present,[1]520–0 Ma[2]
Example of vertebrates: a Siberian tiger (Tetrapoda), an Australian Lungfish (Osteichthyes), a Tiger shark (Chondrichthyes) and a River lamprey (Agnatha).
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Ìjọba:Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará:Chordata
Clade:Olfactores
Subphylum:Vertebrate
J-B. Lamarck, 1801[3]
Simplified grouping (see text)
  • Fishes (cladistically including the Tetrapods)
Synonyms

Ossea Batsch, 1788[3]

Àwọn Ìtọ́ka sí