Ojogbon jé ipò èkó tí o ga jù ní yunifásitì tàbí ilé-èkó miran [1], àwon ojogbon ma ún jé oloye gíga/pupo ní aaye èkó won [2], kí ènìyàn tó Le di ojogbon, o gbodo kókó keko láti di Dokita tí ìmòye(PhD) [3]