Ìbínibí

Ìbínibí je agbajo awon eniyan ti won ni ibapinpo gidi tabi tikosi itan kanna, asa, ede tabi orisun.[1] Idagbasoke ati isegbejadeimo ibínibí je bibatan gbagbagba mo idagbasoke awon isejoba tonile-ese elero ayeodeoni ati awon egbe imurinkankan aseonibinibi ni Europe ni awon odunrun 18jo ati 19sa,[2] botilejepe awon asonibinibi n fa ibinibi lo si ijohun lori ila itan jijapo.[3]




Itokasi