Àwọn Erékùṣù Kánárì
Awon Erekusu Kanari (pípè /kəˈneəriː ˈaɪləndz/; Spánì: [Islas Canarias] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pronounced [ˈizlas kaˈnaɾjas]; 28°06′N 15°24′W / 28.100°N 15.400°W 15°24′W / 28.100°N 15.400°W) je awon ile okan ti orile-ede Spain ti won je okan ninu Spanish Agbajo Adaduro ti Spain ati Agbegbe Ode ninu European Union. Ile okan yi budo si eti ariwaiwoorun bebe orile Afrika, 100 km iwoorun bode to fa ija larin Morocco ati Western Sahara. Iwo okun to yapa lati ebado Kanari lo n mo gbe awon oko oju-omi lo si Amerika.[4] Awon erekusu ibe lati eyi to tobijulo si eyi kerejulo ni wonyi: Tenerife, Fuerteventura, Gran Canaria, Lanzarote, La Palma, La Gomera, El Hierro, Alegranza, La Graciosa ati Montaña Clara.
Canary Islands Islas Canarias | |||
---|---|---|---|
Autonomous Community | |||
| |||
Location of Canary Islands | |||
Country | Spain | ||
Capital | Santa Cruz de Tenerife and Las Palmas de Gran Canaria | ||
Government | |||
• President | Paulino Rivero (CC) | ||
Area (1.5% of Spain; Ranked 13th) | |||
• Total | 7,447 km2 (2,875 sq mi) | ||
Population (2009)[3] | |||
• Total | 2,098,593 | ||
• Density | 280/km2 (730/sq mi) | ||
• Pop. rank | 8th | ||
• Ethnic groups | 85.7% Spanish, (Canarian and Peninsulares), 14.3% foreign nationals | ||
Demonym | |||
ISO 3166-2 | ES-CN | ||
Anthem | Arrorró | ||
Official languages | Spanish | ||
Statute of Autonomy | August 16, 1982 | ||
Parliament | Cortes Generales | ||
Congress seats | 15 | ||
Senate seats | 13 (11 elected, 2 appointed) | ||
Website | Gobierno de Canarias |
Jeografi
Jeografi adanida
Awon erekusu ati awon oluilu won niyi:
Island | Capital |
---|---|
Tenerife | Santa Cruz de Tenerife |
Gran Canaria | Las Palmas de Gran Canaria |
Lanzarote | Arrecife |
La Palma | Santa Cruz de La Palma |
La Gomera | San Sebastián de La Gomera |
El Hierro | Valverde |
Fuerteventura | Puerto del Rosario |
La Graciosa (Lanzarote) | Caleta de Sebo |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |