Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Sàó Tòmẹ̀ àti Principe

Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè São Tomé àti Príncipe lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 2020.[2] The first death was recorded on 30 April.[3]

Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní Sàó Tòmẹ̀ àti Principe
ÀrùnCOVID-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiSão Tomé and Príncipe
Arrival date12 April 2020
(4 years, 2 months and 6 days)
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn741 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje)[1]
Active cases402 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje)
Iye àwọn tí ara wọn ti yá325 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje)
Iye àwọn aláìsí
14 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje)
Official website
Government of São Tomé and Príncipe via Facebook

Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀

Lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà, Covid-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ Hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ WHO lọ́jọ́ kokànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019.[4][5]

Iye ìjàm̀bá ikú àrùn Covid-19 kéré sí ti àrùn SARS, Severe acute respiratory syndrome tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún 2003,[6][7] ṣùgbọ́n jíjàkálẹ̀ àrùn náà lágbára ju SARS lọ, pàápàá jù lọ iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa lápapọ̀.[8][6] Àkọsílẹ̀ kan fihàn pé ìdá 95% confidence interval fún ìyàtọ̀ ìbí ní Sàó Tòmẹ̀ àti Principle kéré ju 1.0 lóṣù Karùn-ún sí kẹfà, ṣùgbọ́n tí ó ti búrẹ́kẹ́ sí i ní ìwọ̀n 1.[9]

Bí àrùn náà ṣe ń búrẹ́kẹ́ sí i láti ìgbà dé ìgbà

COVID-19 cases in São Tomé and Príncipe  ()
     Deaths        Recoveries        Active cases
Date
# of cases
# of deaths
2020-04-06
4(n.a.)
4(=)
2020-04-28
8(+100%)
2020-04-29
11(+38%)
2020-04-30
14(+27%)
2020-05-01
16(+14%)1(n.a.)
2020-05-02
16(=)1(=)
2020-05-03
16(=)1(=)
2020-05-04
23(+44%)3(+200%)
2020-05-05
174(+657%)3(=)
2020-05-06
174(=)3(=)
2020-05-07
187(+7.5%)4(+33%)
2020-05-08
208(+11%)5(+25%)
2020-05-09
208(=)5(=)
2020-05-10
208(=)5(=)
2020-05-11
208(=)5(=)
2020-05-12
208(=)5(=)
2020-05-13
220(+5.8%)6(+20%)
2020-05-14
235(+6.8%)7(+17%)
2020-05-15
235(=)7(=)
2020-05-16
235(=)7(=)
2020-05-17
235(=)7(=)
2020-05-18
246(+4.7%)7(=)
2020-05-19
251(+2%)8(+14%)
2020-05-20
251(=)8(=)
2020-05-21
251(=)8(=)
2020-05-22
251(=)8(=)
2020-05-23
251(=)8(=)
2020-05-24
251(=)8(=)
2020-05-25
299(+19%)11(+38%)
2020-05-26
441(+47%)12(+9.1%)
2020-05-27
443(+0.45%)12(=)
2020-05-28
458(+3.4%)12(=)
2020-05-29
463(+1.1%)12(=)
2020-05-30
479(+3.5%)12(=)
2020-05-31
483(+0.84%)12(=)
2020-06-01
484(+0.21%)12(=)
2020-06-02
484(=)12(=)
2020-06-03
484(=)12(=)
2020-06-04
485(+0.21%)12(=)
2020-06-05
499(+2.9%)12(=)
2020-06-06
499(=)12(=)
2020-06-07
513(+2.8%)12(=)
2020-06-08
513(=)12(=)
2020-06-09
514(+0.19%)12(=)
2020-06-10
611(+19%)12(=)
2020-06-11
632(+3.4%)12(=)
2020-06-12
639(+1.1%)12(=)
2020-06-13
659(+3.1%)12(=)
2020-06-14
661(+0.3%)12(=)
2020-06-15
662(+0.15%)12(=)
2020-06-16
671(+1.4%)12(=)
2020-06-17
683(+1.8%)12(=)
2020-06-18
688(+0.73%)12(=)
2020-06-19
693(+0.73%)12(=)
2020-06-20
693(=)12(=)
2020-06-21
698(+0.72%)12(=)
2020-06-22
702(+0.57%)12(=)
2020-06-23
707(+0.71%)12(=)
2020-06-24
710(+0.42%)13(+8.3%)
2020-06-25
711(+0.14%)13(=)
2020-06-26
712(+0.14%)13(=)
2020-06-27
713(+0.14%)13(=)
2020-06-28
713(=)13(=)
2020-06-29
713(=)13(=)
2020-06-30
714(+0.14%)13(=)
2020-07-01
715(+0.14%)13(=)
2020-07-02
717(+0.28%)13(=)
2020-07-03
719(+0.28%)13(=)
2020-07-04
719(=)13(=)
2020-07-05
720(+0.14%)13(=)
2020-07-06
721(+0.14%)13(=)
2020-07-07
724(+0.42%)13(=)
2020-07-08
724(=)13(=)
2020-07-09
726(+0.28%)14(+7.7%)
2020-07-10
727(+0.14%)14(=)
2020-07-11
727(=)14(=)
2020-07-12
729(+0.28%)14(=)
2020-07-13
732(+0.41%)14(=)
2020-07-14
736(+0.55%)14(=)
2020-07-15
737(+0.14%)14(=)
2020-07-16
740(+0.41%)14(=)
Data sourced from Government of São Tomé and Príncipe via Facebook


Lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 2020 ni orílẹ̀-èdè Sàó-Tòmẹ̀ àti Principe kéde ènìyàn mẹ́rin àkọ́kọ́ tí wọ́n kó àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè náà On. [2]

Àrùn náà pa ẹni àkọ́kọ́ lórílẹ̀-èdè náà lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún náà. Ní àsìkò yìí, Sàó Tòmẹ̀ àti Principe ni ẹni mẹ́rìndínlógún tí wọ́n ti kó àrùn náà, tí ènìyàn mẹ́rin ti rí ìwòsàn, pẹ̀lú àkọsílẹ̀ enikan péré tí àrùn náà pa.[3] Ẹni tí àrùn náà pa jẹ́ ọmọ ọdún márùnléláàádọ́ta tí ó ń gbé ní ìlú Cantalago.[10] Mọ́kànlá ni iye àwọn tí àrùn náà ṣì ń ṣe ní àkókò náà.

Lóṣù karùn-ún ọdún 2020, iye àwọn ènìyàn tuntun tí wọ́n ní àrùn ẹ̀rànkòrónà lórílẹ̀ èdè Sàó Tòmẹ̀ àti Principe jẹ́ 279, tí ènìyàn 9 sìn kú, tí àpapọ̀ àwọn tí wọ́n ní àrùn náà lórílẹ̀ èdè náà jẹ́295, tí àpapọ̀ iye àwọn tí àrùn náà ti pa sìn jẹ́ 10.[11]

Ènìyàn 99 ni wọ́n kéde rẹ̀ pé wọ́n tún kó àrùn náà lóṣù kẹfà pẹ̀lú ẹni kan tí ó tún kú, tí àpapọ̀ iye àwọn tí wọ́n ní àrùn náà 394, pẹ̀lú iye àpapọ̀ àwọn tí wọ́n kú jẹ́ mọ́kànlá, 11.[12]

Ìdènà

Láti dènà jíjàkálẹ̀ àrùn náà, ìjọba orílẹ̀-èdè náà kéde onírúurú ìdádúró àwọn ìrìn-àjò àti ìsémọ́lé lọ́lọ́kanòjọ̀kan.[13]

Àkóbá tó ṣe fún ètò ọ̀rọ̀ ajé

Àkóbá ńlá ni Ìbẹ́sílẹ̀ àrùn náà ṣe fún wọn, nítorí pé ìrìn-àjò afẹ́ kó ìdá ogún nínú àpapọ̀ àwọn iye òṣìṣẹ́ lórílẹ̀ èdè Sàó-Tòmẹ̀ àti Principe, ó fẹ́.ẹ̀ jẹ́ pé gbogbo ibi ìgbà fẹ́ ló ti ilẹ̀kùn wọn pa.[14]

Àwọn Ìtọ́kasí